Others
Olumuyiwa Lyrics by Beautiful Nubia
Beautiful Nubia’s 2023-album, Helen Of Good Tidings, kicks off with the mesmerizing track, Olumuyiwa. Read the lyrics to experience the enchanting words that accompany this beautiful melody.
Beautiful Nubia, Olumuyiwa Lyrics
Jowo, ba mi gb’e’ni mi d’oke odo
O pari ise’ re o, o n dabo’ re ‘le
Olumuyiwa, Iya egbe’ Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re’ o
Olo’ko’, jowo, ba mi s’eni mi ni je’je’
O j’ere l’o’ja o si tun fi’wa lo’gba
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanike’mo nre le o
Jowo, ba mi gb’e’ni mi d’oke odo
O bo’ri idanwo, o ye kooro laye
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re’ o
Oloko, jo’wo’, ba mi s’eni mi ni je’e
O se’won t’o le se o, o la’na ayo’ ka’le’
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanike’mo nre le o
B’o m’orin s’e’nu, b’o se t’adura
Gbogbo ile a mi titi-titi
B’o ba se ka fi’jo se ‘dupe’
E’yin e sa ma wo o
Jowo, ba mi gb’e’ni mi d’oke odo
O pari ise’ re, o n dabo’ re ‘le
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re’ o
Oloko, jo’wo’, ba mi s’eni mi ni je’e
O se’won t’o le se o, o la’na ayo’ ka’le’
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanike’mo nre le o
Jowo, ba mi gb’e’ni mi d’oke odo
O bo’ri idanwo, o ye kooro laye
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re’ o
Oloko, jo’wo’, ba mi s’eni mi ni je’e
O se’won t’o le se o, o la’na ayo’ ka’le’
Olumuyiwa, Iya egbe Oni-ihinrere
Abanike’mo nre le o
B’o m’orin s’e’nu, b’o se t’adura
Gbogbo ile a mi titi-titi
B’oba se ka fi’jo se ‘dupe’
E’yin e sa ma wo o
Jowo, ba mi gb’e’ni mi d’oke odo
O bori idanwo, oyekooro laye
Olumuyiwa, Iya egbe’ Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re’ o
Oloko, jowo, ba mi s’eni mi ni je’je
O sewon to le se o, o lana ayo’ kale’
Olumuyiwa, Iya egbe’ Oni-ihinrere
Abanike’mo nre le o
Olumuyiwa, Iya egbe’ Oni-ihinrere
Abanito’mo nre le re o
Olumuyiwa, Iya egbe’ Oni-ihinrere